هُمُ الَّذِيْنَ يَقُوْلُوْنَ لَا تُنْفِقُوْا عَلٰى مَنْ عِنْدَ رَسُوْلِ اللّٰهِ حَتّٰى يَنْفَضُّوْاۗ وَلِلّٰهِ خَزَاۤىِٕنُ السَّمٰوٰتِ وَالْاَرْضِۙ وَلٰكِنَّ الْمُنٰفِقِيْنَ لَا يَفْقَهُوْنَ
humul-lażīna yaqūlūna lā tunfiqū ‘alā man ‘inda rasūlillāhi ḥattā yanfaḍḍū, wa lillāhi khazā'inus-samāwāti wal-arḍ(i), wa lākinnal-munāfiqīna lā yafqahūn(a).
Àwọn tí wọ́n sọ (fún àwọn ará Ansar), “Ẹ má ṣe fún àwọn ènìyàn (Muhajirín) tí wọ́n wà ní ẹ̀gbẹ́ Òjíṣẹ́ Ọlọ́run ní àánú títí wọn yóò fi túká (fi Òjíṣẹ́ Allah sílẹ̀).” Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìṣúra ọ̀run àti ilẹ̀ ayé jẹ́ ti Allāhu, àwọn alágàbàgebè kò lóye.
يَقُوْلُوْنَ لَىِٕنْ رَّجَعْنَآ اِلَى الْمَدِيْنَةِ لَيُخْرِجَنَّ الْاَعَزُّ مِنْهَا الْاَذَلَّ ۗوَلِلّٰهِ الْعِزَّةُ وَلِرَسُوْلِهٖ وَلِلْمُؤْمِنِيْنَ وَلٰكِنَّ الْمُنٰفِقِيْنَ لَا يَعْلَمُوْنَ ࣖ
yaqūlūna la'ir raja‘nā ilal-madīnati layukhrijannal-a‘azzu minhal-ażall(a), wa lillāhil-‘izzatu wa lirasūlihī wa lil-mu'minīna wa lākinnal-munāfiqīna lā ya‘lamūn(a).
Wọ́n ní, “Dájúdájú, tí a bá padà sí Medina (láti inú ogun àwọn Bani Mustalik), dájúdájú àwọn alágbára yóò lé àwọn aláìlera jáde kúrò níbẹ̀.” Bó tilẹ̀ jẹ́ pé agbára yìí wà fún Allah, Òjíṣẹ́ Rẹ̀ àti àwọn onígbàgbọ́ nìkan, àwọn alágàbàgebè kò mọ̀.