17

Q.S Al-Mujadilah (58:17)

لَنْ تُغْنِيَ عَنْهُمْ اَمْوَالُهُمْ وَلَآ اَوْلَادُهُمْ مِّنَ اللّٰهِ شَيْـًٔاۗ اُولٰۤىِٕكَ اَصْحٰبُ النَّارِۗ هُمْ فِيْهَا خٰلِدُوْنَ

lan tugniya ‘anhum amwāluhum wa lā aulāduhum minallāhi syai'ā(n), ulā'ika aṣḥābun-nār(i), hum fīhā khālidūn(a).

Àwọn dúkìá àti àwọn ọmọ wọn kò wúlò rárá (láti ràn wọ́n lọ́wọ́) kúrò nínú ìyà Allāhu. Àwọn ni olùgbé iná àpáàdì, wọn yóò sì máa gbé ibẹ̀ títí láéláé.