16

Q.S Al-Mujadilah (58:16)

اِتَّخَذُوْٓا اَيْمَانَهُمْ جُنَّةً فَصَدُّوْا عَنْ سَبِيْلِ اللّٰهِ فَلَهُمْ عَذَابٌ مُّهِيْنٌ

ittakhażū aimānahum junnatan fa ṣaddū ‘an sabīlillāhi falahum ‘ażābum muhīn(un).

Wọ́n fi ìbúra wọn ṣe ààbò, lẹ́yìn náà wọ́n ń dí (àwọn ènìyàn) lọ́wọ́ kúrò ní ojú ọ̀nà Allāhu, lẹ́yìn náà ìyà ìtìjú yóò wà fún wọn.