18
Q.S Al-Mujadilah (58:18)
يَوْمَ يَبْعَثُهُمُ اللّٰهُ جَمِيْعًا فَيَحْلِفُوْنَ لَهٗ كَمَا يَحْلِفُوْنَ لَكُمْ وَيَحْسَبُوْنَ اَنَّهُمْ عَلٰى شَيْءٍۗ اَلَآ اِنَّهُمْ هُمُ الْكٰذِبُوْنَ
yauma yab‘aṡuhumullāhu jamī‘an fa yaḥlifūna lahū kamā yaḥlifūna lakum wa yaḥsabūna annahum ‘alā syai'(in), alā innahum humul-kāżibūn(a).
(Ẹ rántí) ọjọ́ tí Allāhu yóò gbé gbogbo wọn dìde, wọn yóò sì búra fún Un (pé wọn kì í ṣe abọ̀rìṣà) gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe búra fún yín, wọ́n sì rò pé àwọn yóò jèrè nǹkan kan (èrè). Ẹ mọ̀ pé àwọn jẹ́ òpùrọ́.