14
Q.S Al-Mujadilah (58:14)
۞ اَلَمْ تَرَ اِلَى الَّذِيْنَ تَوَلَّوْا قَوْمًا غَضِبَ اللّٰهُ عَلَيْهِمْۗ مَا هُمْ مِّنْكُمْ وَلَا مِنْهُمْۙ وَيَحْلِفُوْنَ عَلَى الْكَذِبِ وَهُمْ يَعْلَمُوْنَ
alam tara ilal-lażīna tawallau qauman gaḍiballāhu ‘alaihim, mā hum minkum wa lā minhum, wa yaḥlifūna ‘alal-każibi wa hum ya‘lamūn(a).
Ṣé o kò kíyèsí àwọn (àgàbàgebè) tí wọ́n mú àwọn ènìyàn tí Allāhu ti bínú gẹ́gẹ́ bí ọ̀rẹ́? Àwọn ènìyàn wọ̀nyẹn kì í ṣe láti inú (àwọn ènìyàn) yín, kì í sì í ṣe láti inú (àwọn ènìyàn) wọn. Wọ́n sì ń búra èké, nígbà tí wọ́n mọ̀.