لَقَدْ كَانَ فِيْ قَصَصِهِمْ عِبْرَةٌ لِّاُولِى الْاَلْبَابِۗ مَا كَانَ حَدِيْثًا يُّفْتَرٰى وَلٰكِنْ تَصْدِيْقَ الَّذِيْ بَيْنَ يَدَيْهِ وَتَفْصِيْلَ كُلِّ شَيْءٍ وَّهُدًى وَّرَحْمَةً لِّقَوْمٍ يُّؤْمِنُوْنَ ࣖ
laqad kāna fī qaṣaṣihim ‘ibratul li'ulil-albāb(i), mā kāna ḥadīṡay yuftarā wa lākin taṣdīqal-lażī baina yadaihi wa tafṣīla kulli syai'iw wa hudaw wa raḥmatal liqaumiy yu'minūn(a).
Dájúdájú, ẹ̀kọ́ wà nínú ìtàn wọn fún àwọn ènìyàn tí wọ́n ní làákàyè. (Al-Qur'an) kì í ṣe ìtàn àròsọ, ṣùgbọ́n ó dá àwọn ìwé ìṣáájú (àwọn ìwé) láre, ó ṣàlàyé ohun gbogbo, àti (gẹ́gẹ́ bí) ìtọ́sọ́nà àti àánú fún àwọn tí wọ́n gbàgbọ́.
الَّذِيْنَ اٰمَنُوْا وَتَطْمَىِٕنُّ قُلُوْبُهُمْ بِذِكْرِ اللّٰهِ ۗ اَلَا بِذِكْرِ اللّٰهِ تَطْمَىِٕنُّ الْقُلُوْبُ ۗ
al-lażīna āmanū wa taṭma'innu qulūbuhum biżikrillāh(i), alā biżikrillāhi taṭma'innul-qulūb(u).
(Àmì) àwọn tí ó gbàgbọ́ tí ọkàn wọn sì sinmi nínú ìrántí Allāhu. Wò ó, nínú ìrántí Allāhu nìkan ni ọkàn ti rí ìsinmi.